Nítorí pé kò pa mí ninu oyún,kí inú ìyá mi lè jẹ́ isà òkú fún mi.Kí n wà ninu oyún ninu ìyá mi títí ayé.