Jeremaya 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọlọ́lá ní ìlú rán àwọn iranṣẹ wọn lọ pọn omi,àwọn iranṣẹ dé odò, wọn kò rí omi.Wọ́n gbé ìkòkò omi wọn pada lófìfo,ojú tì wọ́n, ìdààmú dé bá wọn,wọ́n káwọ́ lérí.

Jeremaya 14

Jeremaya 14:1-7