Jeremaya 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Juda ń ṣọ̀fọ̀,àwọn ẹnubodè ìlú rẹ̀ wà ninu ìnira.Àwọn eniyan inú rẹ̀ ń sọkún ní ilẹ̀ẹ́lẹ̀,igbe àwọn ará Jerusalẹmu sì ta sókè.

Jeremaya 14

Jeremaya 14:1-8