Jeremaya 14:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ilẹ̀ tí ó gbẹ,nítorí òjò tí kò rọ̀ ní ilẹ̀ náà,ojú ti àwọn àgbẹ̀, wọ́n káwọ́ lérí.

Jeremaya 14

Jeremaya 14:1-10