Jẹnẹsisi 48:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Josẹfu rí i pé ọwọ́ ọ̀tún ni baba òun gbé lé Efuraimu lórí, kò dùn mọ́ ọn. Ó bá di ọwọ́ baba rẹ̀ mú láti gbé e kúrò lórí Efuraimu kí ó sì gbé e lórí Manase.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:15-22