Jẹnẹsisi 48:16 BIBELI MIMỌ (BM)

kí angẹli tí ó yọ mí ninu gbogbo ewu bukun wọn;kí ìrántí orúkọ mi, ati ti Abrahamu, ati ti Isaaki, àwọn baba mi, wà ní ìran wọn títí ayé,kí atọmọdọmọ wọn pọ̀ lórí ilẹ̀ ayé.”

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:8-22