Jẹnẹsisi 48:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá súre fún Josẹfu, ó ní,“Kí Ọlọrun tí Abrahamu ati Isaaki, baba mi, ń sìn bukun àwọn ọmọ wọnyi,kí Ọlọrun náà tí ó ti ń tọ́ mi ní gbogbo ọjọ́ ayé mi títí di òní yìí bukun wọn,

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:11-17