Jẹnẹsisi 48:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí fún baba rẹ̀ pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́, baba, eléyìí ni àkọ́bí, gbé ọwọ́ ọ̀tún rẹ lé e lórí.”

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:12-22