Jẹnẹsisi 48:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogbó ti mú kí ojú Israẹli di bàìbàì ní àkókò yìí, kò sì ríran dáradára mọ́. Josẹfu bá kó wọn súnmọ́ baba rẹ̀, baba rẹ̀ dì mọ́ wọn, ó sì fi ẹnu kò wọ́n lẹ́nu.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:2-17