Jẹnẹsisi 48:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu dá baba rẹ̀ lóhùn, ó ní, “Àwọn ọmọ mi, tí Ọlọrun pèsè fún mi níhìn-ín ni wọ́n.”Jakọbu bá wí fún un pé, “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí wọ́n súnmọ́ mi kí n lè súre fún wọn.”

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:4-15