Jẹnẹsisi 48:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí fún Josẹfu pé, “N kò lérò pé mo tún lè fi ojú kàn ọ́ mọ́, ṣugbọn Ọlọrun mú kí ó ṣeéṣe fún mi láti rí àwọn ọmọ rẹ.”

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:6-18