Jẹnẹsisi 48:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, wọ́n sọ fún Josẹfu pé ara baba rẹ̀ kò yá, Josẹfu bá mú àwọn ọmọ rẹ̀ mejeeji, Manase ati Efuraimu, lọ́wọ́ lọ bẹ baba rẹ̀ wò.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:1-9