Jẹnẹsisi 48:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n sọ fún Jakọbu pé Josẹfu ọmọ rẹ̀ dé, ó ṣe ara gírí, ó jókòó lórí ibùsùn rẹ̀.

Jẹnẹsisi 48

Jẹnẹsisi 48:1-11