Jẹnẹsisi 47:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu ní kí Josẹfu búra fún òun, Josẹfu sì búra fún un. Nígbà náà ni Jakọbu tẹríba lórí ibùsùn rẹ̀.

Jẹnẹsisi 47

Jẹnẹsisi 47:26-31