Jẹnẹsisi 46:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ tí Josẹfu bí ní Ijipti jẹ́ meji. Gbogbo eniyan tí ó ti ìdílé Jakọbu jáde lọ sí Ijipti patapata wá jẹ́ aadọrin.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:17-33