Jẹnẹsisi 46:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọ́n bá Jakọbu lọ sí Ijipti, tí wọ́n jẹ́ ọmọ tabi ọmọ ọmọ rẹ̀ jẹ́ mẹrindinlaadọrin, láìka àwọn iyawo àwọn ọmọ rẹ̀.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:20-33