Jẹnẹsisi 46:25 BIBELI MIMỌ (BM)

(Àwọn ọmọ tí Biliha bí fún Jakọbu ati àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀ jẹ́ meje), Biliha ni iranṣẹbinrin tí Labani fún Rakẹli, ọmọ rẹ̀ obinrin.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:24-33