Jẹnẹsisi 46:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu rán Juda ṣáájú lọ sọ́dọ̀ Josẹfu pé kí Josẹfu wá pàdé òun ní Goṣeni, wọ́n sì wá sí ilẹ̀ Goṣeni.

Jẹnẹsisi 46

Jẹnẹsisi 46:18-34