Jẹnẹsisi 45:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ni ó rán mi ṣáájú yín láti dá yín sí, ati láti gba ọpọlọpọ ẹ̀mí là ninu ìran yín.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:1-16