Jẹnẹsisi 45:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ó ti di ọdún keji tí ìyàn yìí ti bẹ̀rẹ̀ ní ilẹ̀ yìí, ó sì ku ọdún marun-un gbáko tí kò fi ní sí ìfúrúgbìn tabi ìkórè.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:1-15