Jẹnẹsisi 45:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ẹ má wulẹ̀ dààmú ẹ̀mí ara yín, ẹ má sì bínú sí ara yín pé ẹ tà mí síhìn-ín. Ọlọrun fúnrarẹ̀ ni ó rán mi ṣáájú yín láti gba ẹ̀mí là.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:1-10