Jẹnẹsisi 45:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí gbogbo ìdílé Farao gbọ́ pé àwọn arakunrin Josẹfu dé, inú Farao ati àwọn iranṣẹ rẹ̀ dùn pupọ.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:9-18