Jẹnẹsisi 45:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu bá fi ẹnu ko àwọn arakunrin rẹ̀ lẹ́nu lọ́kọ̀ọ̀kan, ó sì sọkún, lẹ́yìn náà ni àwọn arakunrin rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí bá a sọ̀rọ̀.

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:10-20