Jẹnẹsisi 45:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao sọ fún Josẹfu pé kí ó sọ fún àwọn arakunrin rẹ̀ kí wọ́n múra, kí wọ́n di ẹrù ru àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn, kí wọ́n tètè pada lọ sí Kenaani,

Jẹnẹsisi 45

Jẹnẹsisi 45:9-27