Jẹnẹsisi 44:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n bá bá a lọ́wọ́ èyíkéyìí ninu àwa iranṣẹ rẹ, pípa ni kí wọ́n pa olúwarẹ̀, kí àwa yòókù sì di ẹrú rẹ.”

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:1-12