Jẹnẹsisi 44:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé o ranti pé owó tí a bá lẹ́nu àpò wa, a mú un pada ti ilẹ̀ Kenaani wá fún ọ? Kí ni ìbá dé tí a óo fi jí fadaka tabi wúrà ní ilé ọ̀gá rẹ?

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:1-14