Jẹnẹsisi 44:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn, wọ́n ní, “Èéṣe tí o fi ń sọ̀rọ̀ sí wa báyìí? Kí á má rí i, pé àwa iranṣẹ rẹ ṣe ohun tí ó jọ bẹ́ẹ̀.

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:4-9