Jẹnẹsisi 44:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá wọn lóhùn, ó ní, “Bí ẹ ti wí gan-an ni yóo rí. Ọwọ́ ẹni tí a bá ti bá a ni yóo di ẹrú mi, kò sí ohun tí ó kan ẹ̀yin yòókù rárá.”

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:3-16