Jẹnẹsisi 44:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọ̀rọ̀ wá rí bí ó ti rí yìí, oluwa mi, jọ̀wọ́, jẹ́ kí èmi di ẹrú rẹ dípò ọmọdekunrin yìí, jẹ́ kí òun máa bá àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ pada lọ.

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:31-34