Jẹnẹsisi 44:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi ni mo dúró fún ọmọdekunrin náà lọ́dọ̀ baba wa, mo wí fún un pé, ‘Bí n kò bá mú ọmọ yìí pada, ẹ̀bi rẹ̀ yóo wà lórí mi ní gbogbo ọjọ́ ayé mi.’

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:24-34