Jẹnẹsisi 44:31 BIBELI MIMỌ (BM)

bí kò bá rí i pẹlu wa, kíkú ni yóo kú. Yóo sì wá jẹ́ pé àwa ni a fa ìbànújẹ́ fún baba wa, ní ọjọ́ ogbó rẹ̀, ìbànújẹ́ yìí ni yóo sì pa á.

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:21-34