Jẹnẹsisi 44:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, bí mo bá pada dé ọ̀dọ̀ baba mi tí n kò sì mú ọmọdekunrin náà lọ́wọ́, níwọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ pé ọmọdekunrin yìí gan-an ni ó fi ẹ̀mí tẹ̀,

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:28-31