Jẹnẹsisi 44:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní bí a bá tún mú eléyìí kúrò lọ́dọ̀ òun, bí ohun burúkú kan bá ṣẹlẹ̀ sí i, pẹlu arúgbó ara òun yìí, ìbànújẹ́ rẹ̀ ni yóo pa òun.

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:28-34