Jẹnẹsisi 44:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Báwo ni n óo ṣe pada dé iwájú baba mi láìmú ọmọ náà lọ́wọ́? Ẹ̀rù ohun burúkú tí yóo ṣẹlẹ̀ sí baba mi, ń bà mí.”

Jẹnẹsisi 44

Jẹnẹsisi 44:31-34