Jẹnẹsisi 43:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Josẹfu wọlé, wọ́n mú ẹ̀bùn tí wọ́n mú bọ̀ fún un wọlé tọ̀ ọ́ lọ, wọ́n sì wólẹ̀ fún un, wọ́n dojúbolẹ̀.

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:20-34