Jẹnẹsisi 43:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bèèrè alaafia wọn, ó ní, “Ṣé alaafia ni baba yín wà, arúgbó tí ẹ sọ̀rọ̀ rẹ̀ fún mi? Ṣé ó ṣì wà láàyè?”

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:24-34