Jẹnẹsisi 43:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà wọ́n tọ́jú ẹ̀bùn Josẹfu sílẹ̀ di ìgbà tí yóo dé lọ́sàn-án, nítorí wọ́n gbọ́ pé ibẹ̀ ni wọn yóo ti jẹun.

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:17-34