Jẹnẹsisi 43:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà mú wọn wọ inú ilé Josẹfu, ó fún wọn ní omi, wọ́n fọ ẹsẹ̀ wọn, wọ́n sì fún àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn ní oúnjẹ.

Jẹnẹsisi 43

Jẹnẹsisi 43:20-28