Jẹnẹsisi 41:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao bá sọ fún Josẹfu pé, “Níwọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ pé ìwọ ni Ọlọrun fi gbogbo nǹkan yìí hàn, kò sí ẹni tí ó gbọ́n, tí ó sì lóye bíi rẹ.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:36-42