Jẹnẹsisi 41:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá sọ fún àwọn iranṣẹ rẹ̀ pé, “Ǹjẹ́ a lè rí irú ọkunrin yìí, ẹni tí ẹ̀mí Ọlọrun ń gbé inú rẹ̀?”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:33-40