Jẹnẹsisi 41:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni yóo máa ṣe olórí ilé mi, gbogbo àṣẹ tí o bá sì pa ni àwọn eniyan mi yóo tẹ̀lé, kìkì pé mo jẹ́ ọba nìkan ni n óo fi jù ọ́ lọ.”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:33-48