Jẹnẹsisi 41:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ṣiiri ọkà tí kò níláárí wọnyi gbé àwọn tí wọ́n dára mì. Mo rọ́ àwọn àlá mi fún àwọn adáhunṣe, ṣugbọn kò sí ẹnìkan tí ó lè túmọ̀ wọn fún mi.”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:21-30