Jẹnẹsisi 41:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo tún rí i tí ṣiiri ọkà meje mìíràn yọ lẹ́yìn wọn, wọ́n tínínrín, wọn kò sì ní ọmọ ninu rárá, nítorí afẹ́fẹ́ ìhà ìlà oòrùn ti pa ọlá mọ́ wọn lára.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:20-25