Jẹnẹsisi 41:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu sọ fún Farao, ó ní, “Ọ̀kan náà ni àlá mejeeji, Ọlọrun fi ohun tí ó fẹ́ ṣe han kabiyesi ni.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:23-29