Jẹnẹsisi 41:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao sọ fún un pé, “Mo lá àlá kan, kò sì tíì sí ẹni tí ó lè túmọ̀ rẹ̀. Wọ́n bá sọ fún mi pé, bí o bá gbọ́ àlá, o óo lè túmọ̀ rẹ̀.”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:5-22