Jẹnẹsisi 41:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Josẹfu dá Farao lóhùn, ó ní, “Kò sí ní ìkáwọ́ mi, Ọlọrun ni yóo fún kabiyesi ní ìdáhùn rere.”

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:7-21