Jẹnẹsisi 41:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao bá ranṣẹ lọ pe Josẹfu, wọ́n sì mú un jáde kúrò ninu ẹ̀wọ̀n kíá. Lẹ́yìn tí ó fá irun rẹ̀, tí ó sì pààrọ̀ aṣọ rẹ̀, ó wá siwaju Farao.

Jẹnẹsisi 41

Jẹnẹsisi 41:11-22