Jẹnẹsisi 40:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Alásè rí i pé ìtumọ̀ rẹ̀ dára, ó wí fún Josẹfu pé, “Èmi náà lá àlá kan, mo ru agbọ̀n àkàrà mẹta lórí, lójú àlá.

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:12-23