Jẹnẹsisi 40:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé jíjí ni wọ́n jí mi gbé kúrò ní ilẹ̀ Heberu, ati pé níhìn-ín gan-an, kò sí ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ṣẹ̀ tí wọ́n fi gbé mi jù sẹ́wọ̀n yìí.”

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:12-22