Jẹnẹsisi 40:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ṣá o, ranti mi nígbà tí ó bá dára fún ọ, jọ̀wọ́, ṣe mí lóore kan, ròyìn mi fún Farao, kí Farao sì yọ mí kúrò ninu àhámọ́ yìí.

Jẹnẹsisi 40

Jẹnẹsisi 40:6-18